Iba [Digital Bonus Track]

BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO

Nitori re mo se lo la
Nitori re n mo se n so ge
Nitori re mo se ra moto
Mo wo le, mo boluwa mi soro

Nitori re n mo se wa laiye
Nitori re n mo se wa so sa ra
Nitori re moji lo wu ro
Mo wo aye mi lo de

Aho ha ha a ho
Iba fun eledua
Aho ha ha a ho
Mo wo le mo boluwa mi so ro.

Nitori re n mo n se gbo
Iroyin ayo
Lai so wo, lai si nkon nkon
I ya oni la ayo ola o o
Boluwa se wi be na lo ri

Oh oh o wi kpe kin ma se beru

Aho ha ha a ho,aho
Iba fun eledua
Aho ha ha aho
Mo wo le mo boluwa mi so ro

Ninu ikpon ju
Ninu I damu
Be bi ban kpo na
Ma wo le mo boluwa mi soro

Curiosidades sobre la música Iba [Digital Bonus Track] del Aṣa

¿Quién compuso la canción “Iba [Digital Bonus Track]” de Aṣa?
La canción “Iba [Digital Bonus Track]” de Aṣa fue compuesta por BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO.

Músicas más populares de Aṣa

Otros artistas de Reggae music