Compulsory Course

Zlatan

Ibile
Hayi
Thou shall not carry over
Any course
One unit course
Two units course
Four units course
Ibile ibile wo

Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi
Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi (Hayi hayi wo)

Compulsory course ni ise yin (Mathematics)
Compulsory course ni ise yin (Physics)
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin (Ahn wo)

Lalakukulala
Iwa buruku ba e dagba
Iwo ni vixen
Iwo ni dancer
Mogbo pe o n jijo
You're so bad like that
High like that
Kekere lo ti ja by far
Ise woli ise alfa
Mogbo pe on gbawe adura a gba (Ha)

Sister Veronica (Sister Veronica)
E n je ise laphorita
Home and away le tun ta (Ha)
Market yin ta
Eje mon lo ko kin se omi
Won ni four rounds ko kin yo yin o
Won ti cast ladugbo yin o
Ibile ladugbo yin oo
Foto foto (Foto foto)
O para para (E para pare)
E dara dara (E dara dara)
Bi omi o
Hayi ibile ibile
Eje mon lo ko kin se omi
Won ni four rounds ko kin yo yin o
Won ti cast ladugbo yin o
Hayi ladugbo yin oo
Je o mo

Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi
Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi (Hayi hayi wo)

Compulsory course ni ise yin (Mathematics)
Compulsory course ni ise yin (Physics)
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin (Hayi)

Oro padi o se salaye
Bi adiye se mo fe saba le
E lo mo ma san ti n ba gbara le
Ti ma fi pillow le se ti n ba le
O sa ri bo se mo lololo
Omu ti lo omo ma se fun owo
Ki se a se dagba a se darugbo
Eyi to ba se le lomo ma ko (Ahn)

Sister Veronica (Sister Veronica)
E n je ise laphorita
Home and away le tun ta (Ha)
Market yin ta
Eje mon lo ko kin se omi
Won ni four rounds ko kin yo yin o
Won ti cast ladugbo yin o
Ibile ladugbo yin oo
Foto foto (Foto foto)
O para para (E para pare)
E dara dara (E dara dara)
Bi omi o
Hayi ibile ibile
Eje mon lo ko kin se omi
Won ni four rounds ko kin yo yin o
Won ti cast ladugbo yin o
Hayi ladugbo yin oo
Je o mo

Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi
Aunty (Aunty)
Aunty (Aunty)
Won ba yin soro e n yari (Ha)
Mo fe se yin ni anfani
E te ti ke ti e gbo offer mi (Hayi hayi wo)

Compulsory course ni ise yin (Mathematics)
Compulsory course ni ise yin (Physics)
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Compulsory course ni ise yin
Ko olorun ma je n carry ise yin

Ha ha
Kaka lo tobi to bayi
Ibebe lo tobi to bayi ha
Kaka lo tobi to bayi
Ibebe lo buru to bayi
Kaka lo tobi to bayi
Compulsory course ni ise yi
Mathematics ma teti le o ise yin
Wa mowe me to ba je idi ni mathematics

Curiosidades sobre la música Compulsory Course del Zlatan

¿Cuándo fue lanzada la canción “Compulsory Course” por Zlatan?
La canción Compulsory Course fue lanzada en 2019, en el álbum “Zanku”.

Músicas más populares de Zlatan

Otros artistas de Urban pop music