Malaika

Teni Apata, Oluwademilade Alabi

B'o ti le leju
Wu olorun lo
B'o ti le leju
Wu olorun le

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli Elijah o

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa

I'm at peace with God and at peace with myself
I surrender, I surrender
No weapon fashioned against me shall prosper
Back to sender, back to sender (back to sender oh, moni back to sender oh)

Lord, I give You my heart and my soul and devotion
You give me peace of mind
And I see all Your works and the good that You are doing
Ṣebi na You change my life

Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ

Thank You for all the things that You got me through
Na only me and You
I dey cry night You dey wipe my eyes
Na You dey give me grace o
You say make I get faith o
Make my faith no deflate o

Don't jump from my plate o
People change but You remain the same o
Aimọye eeyan to n ku lojoojumọ
Mi o fi yọ wọn
Mo fi n dupẹ ni
Ẹru n dupẹ ni
Mo fi n dupẹ ni o

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa

Eli Elijah o
Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa

Curiosidades sobre la música Malaika del Teni

¿Cuándo fue lanzada la canción “Malaika” por Teni?
La canción Malaika fue lanzada en 2023, en el álbum “TEARS OF THE SUN”.
¿Quién compuso la canción “Malaika” de Teni?
La canción “Malaika” de Teni fue compuesta por Teni Apata, Oluwademilade Alabi.

Músicas más populares de Teni

Otros artistas de Afrobeats