Orun n Mooru
Olawale Olofo'ro
Teti ko gbo
Ile oba ti gbanna
Awon ijoye won ni kosowo lowo oba
Won soro e leyin
Olori lo n rofo l'oba n san ra
Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo
Oba o gbepo pari, ko binu
O ni kiwon pade ohun laafin
Awon ijoye won tiju bonba r'oba
Won soro e leyin
Olori lo n roka l'oba n san ra
Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo
Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo