Adedotun

Brymo

Verse 1
Awon adan fo loke
Wan foka si oju Orun
Wan o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é Oré o
O wun o n wa
O wa ni waju re

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............

Verse 2
Awon adan fo loke
Ni igba igba
Won ku oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho wan
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo sokoto
O wa lapo Sokoto

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............
(X2)

Ko pamo si é
Oré o
Owun o n wa
O wa ni waju re
Ore o........

Curiosidades sobre la música Adedotun del Brymo

¿Cuándo fue lanzada la canción “Adedotun” por Brymo?
La canción Adedotun fue lanzada en 2020, en el álbum “Yellow”.

Músicas más populares de Brymo

Otros artistas de