Adédọ̀tun [Album]
Olawale Olofo'ro
Awon adan n fo loke
Won fonka soju orun
Un o maa mo ibi won nlo
Eledua lo n seke won
Ko keyin si e
Ore ooo
Ohun o n wa
O wa niwaju re ooo
Adédòtun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo
Awon adan n fo loke
Nigba igba won kun oju orun
Un o maa mo ohun wo n je
Eledua lo n so won lo n bo won
Ko pamo si e
Ore ooo
O wa lo Sokoto
O waa lapo sokoto
Adédòtun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo
Adédòtun
O ooo oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo
Ko pa mo si e
Ore ooo
Ohun o n wa
Owa niwaju re ooo ooo