Ni Bo L’anlo

Wurasamba, Ade Bantu, Oranmiyan, Fatai Rolling Dollar

[Intro: Fatai Rolling Dollar]
A! Ọmọ ẹda ẹwaye tan ẹwa nkanju
Ọlọhun lo ni gbogbo nkan
Ẹma kanju ju kadara a Ẹfọkan balẹ

[Chorus: Oranmiyan]
Ni bo lade, I bo la n lo o
Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
Ka maşe gbagbe ibi ati wa a

[Verse 1: Wurasamba]
Mo ti sọ ọ o, mo ti sọ ifẹ l’eledunmare, mo ti sọ
Otitọ l’eledunmare e, mo ti sọ
Iye l’eledunmare e, mo ti sọ
Imole L’eledunmare o, mo ti sọ
Ka mase gbagbe ibi ati wa a o!
Ka mase gbagbe ibi ati wa a

[Chorus: Oranmiyan]
Ni bo lade, I bo la n lo o
Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
Ka maşe gbagbe ibi ati wa a

[Verse 2: Ade Bantu]
Brother man stay calm relax and free your mind
Reconnect to the source don’t be blind come on
Celebrate how far you’ve gone who you are all the mile that you trekked with the sun
Ain’t nobody gonna stop your shine caus you’re a buffalo soldier, pyramid builder, Afropolitan to the core
Show the world out there that you got more
Reinvoke the spirit of yester years
Gather all the strong ones amongst your peers
It’s a unity thing going on out here
Babylon beware jaga jaga clear better move on or f off or shift your gear caus the tables are turning we’re re- aligning educating ourselves with our elders blessings gotta heed the words of our culture’s calling

[Chorus: Oranmiyan]
Ni bo lade, I bo la n lo o
Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
Ka maşe gbagbe ibi ati wa a

[Verse 3; Fatai Rolling Dollar]
Ẹda o gba kadara nişe naa sare kiiri
Eda o gba kadara nişe naa sare kiiri
Wọn gbagbe ayanmọ, wọn gbagbe işẹ Oluwa Oba
Wọn şe wahala lori asan t’ọba ni oşẹ
Bẹẹfe bẹẹko, T’oluwa ni o şẹ
Ti baba laşẹ, t’oluwa laşẹ o
Mo fẹ d’olowo, mo fẹ d’ọlọla t’oluwa laşẹ
Mo fẹ k’ọle mo fẹ ra mọto t’oluwa laşẹ

Curiosidades sobre la música Ni Bo L’anlo del BANTU (Crew)

¿Cuándo fue lanzada la canción “Ni Bo L’anlo” por BANTU (Crew)?
La canción Ni Bo L’anlo fue lanzada en 2011, en el álbum “No Man Stands Alone”.
¿Quién compuso la canción “Ni Bo L’anlo” de BANTU (Crew)?
La canción “Ni Bo L’anlo” de BANTU (Crew) fue compuesta por Wurasamba, Ade Bantu, Oranmiyan, Fatai Rolling Dollar.

Músicas más populares de BANTU (Crew)

Otros artistas de