Jagun Jagun

Akinkunmi Olagunju, Opeyemi Oyewande, Laolu Ajibade, Peter Sadibo, Olufemi Sanni, Babajide Okegbenro, Adegoke Odukoya, Ibrahim Oyetunji

[Chorus]
Jagun-jagun ló ń bọ̀
Jagun-jagun ló ń bọ̀
Jagun-jagun ló ń bọ̀

[Verse 1: Chant]
Olórí-ogun ò gbọdọ̀ kẹ́yìn ogun
Ọ̀kan ṣoṣo Ẹja tí ń d’abú-omi rú
Ọ̀kan ṣoṣo Ẹfọ̀n tí ń d’ọ̀dàn rú
Ọ̀kan ṣoṣo Àjànàkú tí ń m’igbó kìji-kìji
Jagun-jagun dé, ọmọ ọba kìí jagun bí ẹrú
Òlọ́ṣọmọ́dìí gba ìbọn lọ́wọ́ ọmọ ojo
Jagun-jagun, afiwájúgbọta, afẹ̀yìngbọfà
Jagun-jagun ò fẹ́rọ̀, alágbára èyàn tí ń fi májèlé ròfọ́
Àlùjànú èyàn tí ń fi ọmọ-odó tayín
Bó ṣe ń bá ọmọdé ṣe, bẹ́ẹ̀ ló ń bágbà ṣe
Kọ̀nàn-kọ̀nàn já tòun tòwú
Jagun-aso, ẹkùn ọkọ òkè!
Arọnimaja ṣáagun!
Ó ṣáagun ṣáagun, ó ṣáagun títí, ohun l’awo Alágbàá`a, èyí tí ó fi ta b’aṣeégún lójú

[Chorus]
Jagun-jagun ló ń bọ̀
Jagun-jagun ló ń bọ̀
Jagun-jagun ló ń bọ̀

Curiosidades sobre la música Jagun Jagun del BANTU (Crew)

¿Cuándo fue lanzada la canción “Jagun Jagun” por BANTU (Crew)?
La canción Jagun Jagun fue lanzada en 2020, en el álbum “Everybody Get Agenda”.
¿Quién compuso la canción “Jagun Jagun” de BANTU (Crew)?
La canción “Jagun Jagun” de BANTU (Crew) fue compuesta por Akinkunmi Olagunju, Opeyemi Oyewande, Laolu Ajibade, Peter Sadibo, Olufemi Sanni, Babajide Okegbenro, Adegoke Odukoya, Ibrahim Oyetunji.

Músicas más populares de BANTU (Crew)

Otros artistas de